14 Ní kíá, Dáfídì sọ fún gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù pé: “Ẹ dìde, ẹ sì jẹ́ kí a sá lọ,+ nítorí kò sí ìkankan lára wa tó máa bọ́ lọ́wọ́ Ábúsálómù! Ẹ ṣe kíá, kí ó má bàa yára lé wa bá, kí ó mú àjálù bá wa, kí ó sì fi idà pa ìlú yìí!”+