-
2 Sámúẹ́lì 19:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Síbẹ̀, àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì dá àwọn ọkùnrin Júdà lóhùn pé: “Àwa ní apá mẹ́wàá nínú ìjọba, torí náà ẹ̀tọ́ tí a ní nínú Dáfídì ju tiyín lọ. Kí ló wá dé tí ẹ kò fi kà wá sí? Ṣé kì í ṣe àwa ló yẹ kó kọ́kọ́ mú ọba wa pa dà ni?” Àmọ́ ọ̀rọ̀ àwọn ọkùnrin Júdà borí* ti àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì.
-