Ẹ́kísódù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+ Sáàmù 106:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Sáàmù 114:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Òkun rí i, ó sì sá lọ;+Odò Jọ́dánì yíjú pa dà.+
21 Ni Mósè bá na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;+ Jèhófà sì mú kí atẹ́gùn líle fẹ́ wá láti ìlà oòrùn ní gbogbo òru yẹn, ó sì bi òkun náà sẹ́yìn. Ó mú kí ìsàlẹ̀ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ,+ omi náà sì pínyà.+
9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Sáàmù 114:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Òkun rí i, ó sì sá lọ;+Odò Jọ́dánì yíjú pa dà.+