Mátíù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Aláyọ̀ ni àwọn tí ọkàn wọn mọ́,+ torí wọ́n máa rí Ọlọ́run. 1 Pétérù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 nítorí a ti kọ ọ́ pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́, torí èmi jẹ́ mímọ́.”+