Sáàmù 18:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 O fún mi ní apata rẹ láti gbà mí là,+Ọwọ́ ọ̀tún rẹ ń tì mí lẹ́yìn,*Ìrẹ̀lẹ̀ rẹ sì sọ mí di ẹni ńlá.+ Sáàmù 113:6-8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ 8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.
35 O fún mi ní apata rẹ láti gbà mí là,+Ọwọ́ ọ̀tún rẹ ń tì mí lẹ́yìn,*Ìrẹ̀lẹ̀ rẹ sì sọ mí di ẹni ńlá.+
6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ 8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.