-
Àwọn Onídàájọ́ 8:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Lẹ́yìn náà, Gídíónì dé Jọ́dánì, ó sì sọdá. Ó ti rẹ òun àti ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀, àmọ́ wọn ò dẹ̀yìn lẹ́yìn àwọn tí wọ́n ń lé.
-