2 Sámúẹ́lì 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí Ọba Dáfídì dé Báhúrímù, ọkùnrin ará ilé Sọ́ọ̀lù kan tó ń jẹ́ Ṣíméì+ ọmọ Gérà jáde wá, ó sì ń ṣépè bí ó ṣe ń bọ̀.+ 1 Àwọn Ọba 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ṣíméì ọmọ Gérà ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Báhúrímù náà wà nítòsí rẹ. Òun ló ń ṣẹ́ èpè burúkú+ lé mi lórí lọ́jọ́ tí mò ń lọ sí Máhánáímù;+ àmọ́ nígbà tó wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Jèhófà búra fún un pé: ‘Mi ò ní fi idà pa ọ́.’+
5 Nígbà tí Ọba Dáfídì dé Báhúrímù, ọkùnrin ará ilé Sọ́ọ̀lù kan tó ń jẹ́ Ṣíméì+ ọmọ Gérà jáde wá, ó sì ń ṣépè bí ó ṣe ń bọ̀.+
8 “Ṣíméì ọmọ Gérà ọmọ Bẹ́ńjámínì láti Báhúrímù náà wà nítòsí rẹ. Òun ló ń ṣẹ́ èpè burúkú+ lé mi lórí lọ́jọ́ tí mò ń lọ sí Máhánáímù;+ àmọ́ nígbà tó wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Jèhófà búra fún un pé: ‘Mi ò ní fi idà pa ọ́.’+