9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Áárónì gbé ẹ̀jẹ̀+ ẹran náà wá fún un, ó ki ìka rẹ̀ bọ ẹ̀jẹ̀ náà, ó sì fi sára àwọn ìwo pẹpẹ, ó wá da ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.+
13 “‘Tí ọmọ Ísírẹ́lì kan tàbí àjèjì kan tó ń gbé láàárín yín bá ń ṣọdẹ, tó sì mú ẹran ìgbẹ́ tàbí ẹyẹ tí ẹ lè jẹ, ó gbọ́dọ̀ da ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ jáde,+ kó sì fi erùpẹ̀ bò ó.