Sáàmù 95:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+
7 Nítorí òun ni Ọlọ́run wa,Àwa sì ni èèyàn ibi ìjẹko rẹ̀,Àgùntàn tó wà lábẹ́ àbójútó rẹ̀.*+ Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀,+