1 Àwọn Ọba 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó sì sọ pé: “Jọ̀wọ́, sọ fún Sólómọ́nì ọba pé kó fún mi ní Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù láti fi ṣe aya. Mo mọ̀ pé kò ní da ọ̀rọ̀ rẹ nù.” 1 Àwọn Ọba 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”
17 Ó sì sọ pé: “Jọ̀wọ́, sọ fún Sólómọ́nì ọba pé kó fún mi ní Ábíṣágì+ ará Ṣúnémù láti fi ṣe aya. Mo mọ̀ pé kò ní da ọ̀rọ̀ rẹ nù.”
22 Ni Ọba Sólómọ́nì bá dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé: “Kí ló dé tí o fi ní kí n fún Ádóníjà ní Ábíṣágì ará Ṣúnémù? Ò bá kúkú ní kí n fún un ní ìjọba pẹ̀lú+ nítorí pé ẹ̀gbọ́n mi ni,+ ẹ̀yìn rẹ̀ sì ni àlùfáà Ábíátárì àti Jóábù+ ọmọ Seruáyà+ wà.”