1 Àwọn Ọba 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn akèrègbè+ àti ìtànná òdòdó+ ni wọ́n gbẹ́ sára igi kédárì tí ó wà nínú ilé náà. Gbogbo rẹ̀ jẹ́ igi kédárì; kò sí òkúta kankan tí a rí.
18 Àwọn akèrègbè+ àti ìtànná òdòdó+ ni wọ́n gbẹ́ sára igi kédárì tí ó wà nínú ilé náà. Gbogbo rẹ̀ jẹ́ igi kédárì; kò sí òkúta kankan tí a rí.