Jeremáyà 52:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n tún kó àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà, àwọn abọ́,+ àwọn ife+ àti gbogbo nǹkan èlò bàbà tí wọ́n ń lò nínú tẹ́ńpìlì.
18 Wọ́n tún kó àwọn garawa, àwọn ṣọ́bìrì, àwọn ohun tí wọ́n fi ń pa fìtílà, àwọn abọ́,+ àwọn ife+ àti gbogbo nǹkan èlò bàbà tí wọ́n ń lò nínú tẹ́ńpìlì.