1 Àwọn Ọba 1:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ọba sọ fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín dání, kí ẹ sì ní kí Sólómọ́nì ọmọ mi gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tèmi fúnra mi,+ kí ẹ wá mú un lọ sí Gíhónì.+ Mátíù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n mú kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà àti ọmọ rẹ̀ wá, wọ́n tẹ́ aṣọ àwọ̀lékè wọn sórí wọn, ó sì jókòó sórí wọn.+
33 Ọba sọ fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ olúwa yín dání, kí ẹ sì ní kí Sólómọ́nì ọmọ mi gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* tèmi fúnra mi,+ kí ẹ wá mú un lọ sí Gíhónì.+