1 Kíróníkà 29:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọlọ́run mi, mo mọ̀ dáadáa pé o máa ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti pé o fẹ́ràn ìwà títọ́.*+ Nínú òótọ́* ọkàn ni mo fínnú-fíndọ̀ pèsè gbogbo nǹkan yìí, ayọ̀ mi sì kún láti rí àwọn èèyàn rẹ tó wá síbí láti ṣe ọrẹ àtinúwá fún ọ.
17 Ọlọ́run mi, mo mọ̀ dáadáa pé o máa ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti pé o fẹ́ràn ìwà títọ́.*+ Nínú òótọ́* ọkàn ni mo fínnú-fíndọ̀ pèsè gbogbo nǹkan yìí, ayọ̀ mi sì kún láti rí àwọn èèyàn rẹ tó wá síbí láti ṣe ọrẹ àtinúwá fún ọ.