1 Àwọn Ọba 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Áhíṣà ló ń bójú tó agbo ilé; Ádónírámù+ ọmọ Ábídà ni olórí àwọn tí ọba ní kí ó máa ṣiṣẹ́ fún òun.+ 1 Àwọn Ọba 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọba Sólómọ́nì ní kí àwọn ọkùnrin kan láti gbogbo Ísírẹ́lì máa ṣiṣẹ́ fún òun;+ wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) ọkùnrin.
13 Ọba Sólómọ́nì ní kí àwọn ọkùnrin kan láti gbogbo Ísírẹ́lì máa ṣiṣẹ́ fún òun;+ wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) ọkùnrin.