-
2 Kíróníkà 9:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Yàtọ̀ síyẹn, àwọn ìránṣẹ́ Hírámù àti àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì tí wọ́n kó wúrà wá láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù àti àwọn òkúta iyebíye wá.+ 11 Ọba fi àwọn gẹdú igi álígọ́mù náà ṣe àtẹ̀gùn sí ilé Jèhófà+ àti sí ilé* ọba,+ títí kan àwọn háàpù àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín fún àwọn akọrin.+ A kò rí irú àwọn nǹkan yìí rí ní ilẹ̀ Júdà.
-