Jẹ́nẹ́sísì 26:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Nígbà tí Ísọ̀ pé ẹni ogójì (40) ọdún, ó fi Júdítì ọmọ Béérì, ọmọ Hétì ṣe aya àti Básémátì ọmọ Ẹ́lónì, ọmọ Hétì.+ 35 Wọ́n ba Ísákì àti Rèbékà+ nínú jẹ́* gidigidi.
34 Nígbà tí Ísọ̀ pé ẹni ogójì (40) ọdún, ó fi Júdítì ọmọ Béérì, ọmọ Hétì ṣe aya àti Básémátì ọmọ Ẹ́lónì, ọmọ Hétì.+ 35 Wọ́n ba Ísákì àti Rèbékà+ nínú jẹ́* gidigidi.