-
2 Sámúẹ́lì 8:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Òkìkí Dáfídì túbọ̀ kàn nígbà tí ó pa dà láti ibi tó ti lọ pa ẹgbẹ̀rún méjìdínlógún (18,000) lára àwọn ọmọ Édómù ní Àfonífojì Iyọ̀.+
-