2 Sámúẹ́lì 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́+ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Màá sì fún ọ ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ “‘“Yàtọ̀ síyẹn, Jèhófà sọ fún ọ pé, Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.*+
11 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́+ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Màá sì fún ọ ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ “‘“Yàtọ̀ síyẹn, Jèhófà sọ fún ọ pé, Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.*+