-
2 Àwọn Ọba 17:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ó fa Ísírẹ́lì ya kúrò ní ilé Dáfídì, wọ́n sì fi Jèróbóámù ọmọ Nébátì jọba.+ Àmọ́ Jèróbóámù mú kí Ísírẹ́lì yà kúrò lẹ́yìn Jèhófà, ó sì mú kí wọ́n dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.
-