33 Kódà lẹ́yìn tí nǹkan yìí ṣẹlẹ̀, Jèróbóámù kò yí pa dà kúrò nínú ọ̀nà búburú rẹ̀, ńṣe ló ń yan ẹnikẹ́ni lára àwọn èèyàn náà láti fi ṣe àlùfáà ní àwọn ibi gíga.+ Ẹni tí ó bá wù ú ló máa ń fi ṣe àlùfáà, á sì sọ pé: “Jẹ́ kó di ọ̀kan lára àwọn àlùfáà ibi gíga.”+