-
1 Àwọn Ọba 20:35, 36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Jèhófà bá ọ̀kan lára àwọn ọmọ wòlíì* sọ̀rọ̀,+ ni ó bá sọ fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lù mí.” Àmọ́ ọkùnrin náà kọ̀, kò lù ú. 36 Nítorí náà, ó sọ fún un pé: “Torí pé o kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, gbàrà tí o bá ti kúrò lọ́dọ̀ mi, kìnnìún yóò pa ọ.”* Lẹ́yìn tí ó kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, kìnnìún kan yọ sí i, ó sì pa á.
-