25 Bí àpẹẹrẹ, mò ń sọ fún yín ní tòótọ́ pé: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ opó ló wà ní Ísírẹ́lì nígbà ayé Èlíjà, nígbà tí a sé ọ̀run pa fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà, tí ìyàn sì mú gidigidi ní gbogbo ilẹ̀ náà.+
17 Ẹni tó máa ń mọ nǹkan lára bíi tiwa ni Èlíjà, síbẹ̀, nígbà tó gbàdúrà taratara pé kí òjò má rọ̀, òjò ò rọ̀ sórí ilẹ̀ náà fún ọdún mẹ́ta àti oṣù mẹ́fà.+