2 Sámúẹ́lì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* lákòókò tí àwọn ọba máa ń jáde ogun, Dáfídì rán Jóábù àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì pé kí wọ́n lọ pa àwọn ọmọ Ámónì run, wọ́n sì dó ti Rábà,+ àmọ́ Dáfídì dúró sí Jerúsálẹ́mù.+
11 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* lákòókò tí àwọn ọba máa ń jáde ogun, Dáfídì rán Jóábù àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì pé kí wọ́n lọ pa àwọn ọmọ Ámónì run, wọ́n sì dó ti Rábà,+ àmọ́ Dáfídì dúró sí Jerúsálẹ́mù.+