-
1 Àwọn Ọba 1:51, 52Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Wọ́n wá ròyìn fún Sólómọ́nì pé: “Wò ó, ẹ̀rù Ọba Sólómọ́nì ti ń ba Ádóníjà; ó sì ti lọ gbá àwọn ìwo pẹpẹ mú, ó sọ pé, ‘Kí Ọba Sólómọ́nì kọ́kọ́ búra fún mi pé òun ò ní fi idà pa ìránṣẹ́ rẹ̀.’” 52 Ni Sólómọ́nì bá sọ pé: “Tí kò bá kọjá àyè rẹ̀, kò sí ìkankan nínú irun orí rẹ̀ tó máa bọ́ sílẹ̀; àmọ́ tí a bá rí ohun tí kò dára lọ́wọ́ rẹ̀,+ ó gbọ́dọ̀ kú.”
-