-
Léfítíkù 14:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kó wá wọ́n ọn lẹ́ẹ̀méje sára ẹni tó fẹ́ wẹ ara rẹ̀ mọ́ kúrò nínú ẹ̀tẹ̀, kó sì kéde pé ẹni náà ti di mímọ́, kó sì tú ààyè ẹyẹ náà sílẹ̀ lórí pápá gbalasa.+
-
-
Nọ́ńbà 19:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kí àlùfáà Élíásárì wá fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ ẹran náà, kó sì wọ́n ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lẹ́ẹ̀méje, sí ọ̀ọ́kán iwájú àgọ́+ ìjọsìn.
-