-
1 Àwọn Ọba 18:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ṣé wọn ò tíì sọ ohun tí mo ṣe fún olúwa mi nígbà tí Jésíbẹ́lì ń pa àwọn wòlíì Jèhófà ni, bí mo ṣe kó ọgọ́rùn-ún (100) lára àwọn wòlíì Jèhófà pa mọ́, ní àádọ́ta-àádọ́ta sínú ihò, tí mo sì ń fún wọn ní oúnjẹ àti omi?+
-