-
Jóṣúà 8:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ó pàṣẹ fún wọn pé: “Ẹ wò ó, ẹ lúgọ sí ẹ̀yìn ìlú náà. Ẹ má jìnnà jù sí ìlú náà, kí gbogbo yín sì múra sílẹ̀.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 20:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ísírẹ́lì wá ní kí àwọn ọkùnrin lọ lúgọ+ yí Gíbíà ká.
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 20:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Àwọn tó lúgọ náà ò fi nǹkan falẹ̀ rárá, wọ́n yára sún mọ́ Gíbíà. Wọ́n wá pín ara wọn yí ká ìlú náà, wọ́n sì fi idà ṣá gbogbo ìlú náà balẹ̀.
-