-
1 Àwọn Ọba 16:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ní ọdún kẹrìndínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, Élà ọmọ Bááṣà di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Tírísà, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso.
-
-
1 Àwọn Ọba 16:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Símírì wọlé, ó ṣá a balẹ̀,+ ó sì pa á ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Ásà ọba Júdà, ó sì jọba ní ipò rẹ̀.
-