-
Ẹ́kísódù 32:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Lẹ́yìn náà, Mósè dúró ní ẹnubodè àgọ́ náà, ó sì sọ pé: “Ta ló fara mọ́ Jèhófà? Kó máa bọ̀ lọ́dọ̀ mi!”+ Gbogbo àwọn ọmọ Léfì sì kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀.
-
-
Sáàmù 94:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ta ló máa bá mi dìde sí ẹni burúkú?
Ta ló máa gbèjà mi níwájú àwọn aṣebi?
-