2 Àwọn Ọba 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọdún kẹtàlélógún Jèhóáṣì+ ọmọ Ahasáyà+ ọba Júdà, Jèhóáhásì ọmọ Jéhù+ di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ọdún mẹ́tàdínlógún (17) ló sì fi ṣàkóso.
13 Ní ọdún kẹtàlélógún Jèhóáṣì+ ọmọ Ahasáyà+ ọba Júdà, Jèhóáhásì ọmọ Jéhù+ di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ọdún mẹ́tàdínlógún (17) ló sì fi ṣàkóso.