-
2 Àwọn Ọba 11:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àmọ́, Jèhóṣébà ọmọbìnrin Ọba Jèhórámù, arábìnrin Ahasáyà, gbé Jèhóáṣì+ ọmọ Ahasáyà, ó jí i gbé láàárín àwọn ọmọ ọba tí wọ́n fẹ́ pa, ó fi òun àti obìnrin tó ń tọ́jú rẹ̀ pa mọ́ sínú yàrá inú lọ́hùn-ún. Wọ́n sì rọ́nà fi í pa mọ́ kí Ataláyà má bàa rí i, torí náà kò rí i pa.
-