-
2 Àwọn Ọba 22:4-6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+ 5 Ní kí wọ́n kó o fún àwọn tí wọ́n yàn láti máa bójú tó iṣẹ́ ilé Jèhófà, àwọn yìí ló máa fún àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nínú ilé Jèhófà láti tún àwọn ibi tó bà jẹ́* lára ilé náà ṣe,+ 6 ìyẹn àwọn oníṣẹ́ ọnà àti àwọn kọ́lékọ́lé àti àwọn mọlémọlé; owó yìí ni kí wọ́n fi ra àwọn ẹ̀là gẹdú àti àwọn òkúta gbígbẹ́ tí wọ́n á fi tún ilé náà ṣe.+
-
-
2 Kíróníkà 24:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn náà, ọba àti Jèhóádà á kó o fún àwọn tó ń bójú tó iṣẹ́ ìsìn ilé Jèhófà, wọ́n á sì háyà àwọn agékùúta àti àwọn oníṣẹ́ ọnà láti tún ilé Jèhófà ṣe,+ títí kan àwọn oníṣẹ́ irin àti bàbà láti tún ilé Jèhófà ṣe.
-