2 Àwọn Ọba 14:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ní ti ìyókù ìtàn Jèróbóámù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti agbára rẹ̀, bí ó ṣe jà àti bí ó ṣe gba Damásíkù+ àti Hámátì+ pa dà fún Júdà ní Ísírẹ́lì, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Ísírẹ́lì?
28 Ní ti ìyókù ìtàn Jèróbóámù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti agbára rẹ̀, bí ó ṣe jà àti bí ó ṣe gba Damásíkù+ àti Hámátì+ pa dà fún Júdà ní Ísírẹ́lì, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Ísírẹ́lì?