-
2 Àwọn Ọba 4:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Torí náà, ó lọ sọ́dọ̀ èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ní Òkè Kámẹ́lì. Bí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ ṣe rí i lọ́ọ̀ọ́kán, ó sọ fún Géhásì, ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Wò ó! Obìnrin ará Ṣúnémù yẹn ló ń bọ̀ yìí.
-