Ẹ́kísódù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+ Àwọn Onídàájọ́ 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n wá kó àwọn ọlọ́run àjèjì kúrò láàárín wọn, wọ́n sì ń sin Jèhófà,+ débi pé ojú rẹ̀ ò gbà á mọ́* bí Ísírẹ́lì ṣe ń jìyà.+ Sáàmù 106:43, 44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+ 44 Àmọ́ á tún rí ìdààmú tó bá wọn,+Á sì gbọ́ igbe ìrànlọ́wọ́ wọn.+
7 Jèhófà sì sọ pé: “Mo ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn èèyàn mi ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ igbe wọn torí àwọn tó ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́; mo mọ̀ dáadáa pé wọ́n ń jẹ̀rora.+
16 Wọ́n wá kó àwọn ọlọ́run àjèjì kúrò láàárín wọn, wọ́n sì ń sin Jèhófà,+ débi pé ojú rẹ̀ ò gbà á mọ́* bí Ísírẹ́lì ṣe ń jìyà.+
43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+ 44 Àmọ́ á tún rí ìdààmú tó bá wọn,+Á sì gbọ́ igbe ìrànlọ́wọ́ wọn.+