2 Àwọn Ọba 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, ó kú, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu Èlíjà sọ. Àmọ́ torí pé kò ní ọmọkùnrin kankan, Jèhórámù*+ jọba ní ipò rẹ̀, ní ọdún kejì Jèhórámù+ ọmọ Jèhóṣáfátì ọba Júdà.
17 Torí náà, ó kú, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà gbẹnu Èlíjà sọ. Àmọ́ torí pé kò ní ọmọkùnrin kankan, Jèhórámù*+ jọba ní ipò rẹ̀, ní ọdún kejì Jèhórámù+ ọmọ Jèhóṣáfátì ọba Júdà.