-
2 Kíróníkà 31:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Gbàrà tí wọ́n parí gbogbo èyí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ jáde lọ sí àwọn ìlú Júdà, wọ́n fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà sí wẹ́wẹ́,+ wọ́n gé àwọn òpó òrìṣà lulẹ̀,*+ wọ́n sì wó àwọn ibi gíga+ àti àwọn pẹpẹ+ lulẹ̀ ní gbogbo Júdà àti Bẹ́ńjámínì pẹ̀lú Éfúrémù àti Mánásè+ títí wọ́n fi pa wọ́n run pátápátá, lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pa dà sí àwọn ìlú wọn, kálukú pa dà sídìí ohun ìní rẹ̀.
-