Ẹ́sírà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà ayé Atasásítà ọba Páṣíà, Bíṣílámù, Mítírédátì, Tábéélì àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ yòókù kọ̀wé sí Ọba Atasásítà; wọ́n túmọ̀ lẹ́tà náà sí èdè Árámáíkì,+ ọ̀nà ìkọ̀wé èdè Árámáíkì ni wọ́n sì fi kọ ọ́.* Dáníẹ́lì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ará Kálídíà fún ọba lésì ní èdè Árámáíkì+ pé:* “Kí ẹ̀mí ọba gùn títí láé. Rọ́ àlá náà fún àwa ìránṣẹ́ rẹ, a sì máa sọ ìtumọ̀ rẹ̀.”
7 Nígbà ayé Atasásítà ọba Páṣíà, Bíṣílámù, Mítírédátì, Tábéélì àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ yòókù kọ̀wé sí Ọba Atasásítà; wọ́n túmọ̀ lẹ́tà náà sí èdè Árámáíkì,+ ọ̀nà ìkọ̀wé èdè Árámáíkì ni wọ́n sì fi kọ ọ́.*
4 Àwọn ará Kálídíà fún ọba lésì ní èdè Árámáíkì+ pé:* “Kí ẹ̀mí ọba gùn títí láé. Rọ́ àlá náà fún àwa ìránṣẹ́ rẹ, a sì máa sọ ìtumọ̀ rẹ̀.”