Sáàmù 83:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí ojú tì wọ́n, kí jìnnìjìnnì sì bá wọn títí láé;Kí wọ́n tẹ́, kí wọ́n sì ṣègbé;18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Àìsáyà 45:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì. Kò sí Ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Màá fún ọ lókun,* bó ò tiẹ̀ mọ̀ mí, 6 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀,Láti ibi tí oòrùn ti ń yọ, dé ibi tó ti ń wọ̀*Pé kò sí ẹnì kankan yàtọ̀ sí mi.+ Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì.+
17 Kí ojú tì wọ́n, kí jìnnìjìnnì sì bá wọn títí láé;Kí wọ́n tẹ́, kí wọ́n sì ṣègbé;18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+
5 Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì. Kò sí Ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Màá fún ọ lókun,* bó ò tiẹ̀ mọ̀ mí, 6 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀,Láti ibi tí oòrùn ti ń yọ, dé ibi tó ti ń wọ̀*Pé kò sí ẹnì kankan yàtọ̀ sí mi.+ Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì.+