2 Kíróníkà 32:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó tún kọ àwọn lẹ́tà+ láti fi pẹ̀gàn Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti láti fi sọ̀rọ̀ òdì sí i, ó ní: “Bí àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè kò ṣe gba àwọn èèyàn wọn lọ́wọ́ mi,+ bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run Hẹsikáyà kò ní gba àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi.” Àìsáyà 10:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọwọ́ mi tẹ ìjọba àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,Àwọn tí ère gbígbẹ́ wọn pọ̀ ju ti Jerúsálẹ́mù àti Samáríà lọ!+ 11 Ǹjẹ́ kì í ṣe ohun tí mo ṣe sí Samáríà àti àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò ní láárí gẹ́lẹ́Ni màá ṣe sí Jerúsálẹ́mù àti àwọn òrìṣà rẹ̀?’+
17 Ó tún kọ àwọn lẹ́tà+ láti fi pẹ̀gàn Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì+ àti láti fi sọ̀rọ̀ òdì sí i, ó ní: “Bí àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè kò ṣe gba àwọn èèyàn wọn lọ́wọ́ mi,+ bẹ́ẹ̀ ni Ọlọ́run Hẹsikáyà kò ní gba àwọn èèyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi.”
10 Ọwọ́ mi tẹ ìjọba àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí,Àwọn tí ère gbígbẹ́ wọn pọ̀ ju ti Jerúsálẹ́mù àti Samáríà lọ!+ 11 Ǹjẹ́ kì í ṣe ohun tí mo ṣe sí Samáríà àti àwọn ọlọ́run rẹ̀ tí kò ní láárí gẹ́lẹ́Ni màá ṣe sí Jerúsálẹ́mù àti àwọn òrìṣà rẹ̀?’+