1 Àwọn Ọba 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Mo ṣì ní ẹgbẹ̀rún méje (7,000) èèyàn ní Ísírẹ́lì,+ tí gbogbo wọn ò kúnlẹ̀ fún Báálì,+ tí wọn ò sì fẹnu kò ó lẹ́nu.”+
18 Mo ṣì ní ẹgbẹ̀rún méje (7,000) èèyàn ní Ísírẹ́lì,+ tí gbogbo wọn ò kúnlẹ̀ fún Báálì,+ tí wọn ò sì fẹnu kò ó lẹ́nu.”+