ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 17:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “Dìde, lọ sí Sáréfátì, ti Sídónì, kí o sì máa gbé ibẹ̀. Wò ó! Màá pàṣẹ fún opó kan níbẹ̀, pé kí ó máa gbé oúnjẹ wá fún ọ.”+

  • 1 Àwọn Ọba 17:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Obìnrin náà wá sọ pé: “Bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti wà láàyè, mi ò ní búrẹ́dì kankan, àfi ẹ̀kúnwọ́ ìyẹ̀fun nínú ìkòkò àti òróró díẹ̀ nínú ìṣà kékeré.+ Ńṣe ni mò ń ṣa igi díẹ̀ jọ, kí n lè wọlé lọ ṣe nǹkan díẹ̀ fún èmi àti ọmọ mi. Lẹ́yìn tí a bá ti jẹ ẹ́ tán, a ò ní nǹkan míì, ikú ló kàn.”

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́