Jeremáyà 41:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n lọ, wọ́n sì dé sí ibùwọ̀ Kímúhámù tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ láti lọ sí Íjíbítì+ 18 torí àwọn ará Kálídíà. Ẹ̀rù wọn ń bà wọ́n, nítorí Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà ti pa Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù, ẹni tí ọba Bábílónì yàn ṣe olórí ilẹ̀ náà.+
17 Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n lọ, wọ́n sì dé sí ibùwọ̀ Kímúhámù tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ láti lọ sí Íjíbítì+ 18 torí àwọn ará Kálídíà. Ẹ̀rù wọn ń bà wọ́n, nítorí Íṣímáẹ́lì ọmọ Netanáyà ti pa Gẹdaláyà ọmọ Áhíkámù, ẹni tí ọba Bábílónì yàn ṣe olórí ilẹ̀ náà.+