Jóṣúà 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jóṣúà wá súre fún un, ó sì fún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ní Hébúrónì pé kó jẹ́ ogún rẹ̀.+ Àwọn Onídàájọ́ 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wọ́n fún Kélẹ́bù ní Hébúrónì, bí Mósè ṣe ṣèlérí,+ ó sì lé àwọn ọmọ Ánákì+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta kúrò níbẹ̀.