Nọ́ńbà 35:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí àwọn ìlú yìí jẹ́ ìlú ààbò fún yín lọ́wọ́ ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀,+ kí apààyàn náà má bàa kú kí wọ́n tó gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú àpéjọ+ náà. 13 Ohun tí àwọn ìlú mẹ́fẹ̀ẹ̀fà tí ẹ yàn pé kó jẹ́ ibi ààbò máa wà fún nìyẹn.
12 Kí àwọn ìlú yìí jẹ́ ìlú ààbò fún yín lọ́wọ́ ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀,+ kí apààyàn náà má bàa kú kí wọ́n tó gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú àpéjọ+ náà. 13 Ohun tí àwọn ìlú mẹ́fẹ̀ẹ̀fà tí ẹ yàn pé kó jẹ́ ibi ààbò máa wà fún nìyẹn.