Jẹ́nẹ́sísì 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà fi àjàkálẹ̀ àrùn* kọ lu Fáráò àti agbo ilé rẹ̀ nítorí Sáráì, ìyàwó Ábúrámù.+ Jẹ́nẹ́sísì 20:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run bá Ábímélékì sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru, ó sọ fún un pé: “Wò ó, o ti kú tán torí obìnrin tí o mú yìí,+ ó ti lọ́kọ, ìyàwó oníyàwó+ sì ni.”
3 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run bá Ábímélékì sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru, ó sọ fún un pé: “Wò ó, o ti kú tán torí obìnrin tí o mú yìí,+ ó ti lọ́kọ, ìyàwó oníyàwó+ sì ni.”