-
Diutarónómì 26:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ní báyìí, mo ti mú àkọ́so èso ilẹ̀ tí Jèhófà fún mi wá.’+
“Kí o kó o síwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ, kí o sì tẹrí ba níwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.
-