8 Dáfídì àti gbogbo Ísírẹ́lì ń ṣe ayẹyẹ níwájú Ọlọ́run tòótọ́ tọkàntara pẹ̀lú orin, háàpù, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín, ìlù tanboríìnì+ àti síńbálì*+ pẹ̀lú kàkàkí.+
16 Dáfídì wá sọ fún àwọn olórí ọmọ Léfì pé kí wọ́n yan àwọn arákùnrin wọn tó jẹ́ akọrin láti máa fi ayọ̀ kọrin, kí wọ́n máa lo àwọn ohun ìkọrin, ìyẹn àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ pẹ̀lú síńbálì.*+
5 Ásáfù+ ni olórí, Sekaráyà ni igbá kejì rẹ̀; Jéélì, Ṣẹ́mírámótì, Jéhíélì, Matitáyà, Élíábù, Bẹnáyà, Obedi-édómù àti Jéélì+ ń ta àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù;+ Ásáfù ń lo síńbálì,*+