2 Sámúẹ́lì 23:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú+ nìyí: Joṣebi-báṣébétì tó jẹ́ Tákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ (800) ọkùnrin. 2 Sámúẹ́lì 23:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Hélésì+ tó jẹ́ Pálútì, Írà+ ọmọ Íkéṣì ará Tékóà,
8 Orúkọ àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú+ nìyí: Joṣebi-báṣébétì tó jẹ́ Tákímónì, olórí àwọn mẹ́ta náà.+ Ìgbà kan wà tó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́jọ (800) ọkùnrin.